August 6-12
Lúùkù 17-18
Orin 18 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Máa Dúpẹ́ Oore”: (10 min.)
Lk 17:11-14—Jésù wo àwọn adẹ́tẹ̀ mẹ́wàá sàn (“àwọn ọkùnrin adẹ́tẹ̀ mẹ́wàá,” “Glossary Ẹ̀tẹ̀; Adẹ́tẹ̀,” Mt 8:2; adẹ́tẹ̀,” “lọ fi ara rẹ han àlùfáà” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 17:12, 14, nwtsty)
Lk 17:15, 16—Ọ̀kan lára àwọn adẹ́tẹ̀ náà ló pa dà wá dúpẹ́ lọ́wọ́ Jésù
Lk 17:17, 18—Ìtàn yìí jẹ́ ká rí ìdí tó fi yẹ ká máa dúpẹ́ oore (w08 8/1 14-15 ¶8-9)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Lk 17:7-10—Kí ni Jésù fẹ́ fà yọ nínú àpèjúwe yìí? (“tí kò dára fún ohunkóhun” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 17:10, nwtsty)
Lk 18:8—Irú ìgbàgbọ́ wo ni Jésù ń sọ nínú ẹsẹ yìí? (“ìgbàgbọ́” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 18:8, nwtsty)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lk 18:24-43
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Wo Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 4 ¶1-2
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ẹ Rántí Aya Lọ́ọ̀tì”: (15 min.) Ìjíròrò.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 11 ¶10-19
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 117 àti Àdúrà