August 20-26
Lúùkù 21-22
Orin 27 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ìdáǹdè Yín Ń Sún Mọ́lé”: (10 min.)
Lk 21:25—Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ gbankọgbì máa ṣẹlẹ̀ nígbà ìpọ́njú ńlá (kr 226 ¶9)
Lk 21:26—Jìnnìjìnnì máa bo àwọn ọ̀tá Jèhófà
Lk 21:27, 28—Jésù máa wá láti gba àwọn olóòótọ́ là (w16.01 7 ¶17; w15 7/15 17-18 ¶13)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Lk 21:33—Báwo ló ṣe yẹ ká lóye ọ̀rọ̀ Jésù yìí? (“Ọ̀run àti ilẹ̀ ayé yóò kọjá lọ,” “àwọn ọ̀rọ̀ mi kì yóò kọjá lọ lọ́nàkọnà” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 21:33, nwtsty)
Lk 22:28-30—Májẹ̀mú wo ni Jésù dá, àwọn wo ló bá dá a, kí ló sì ṣàṣeparí rẹ̀? (w14 10/15 16-17 ¶15-16)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lk 22:35-53
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Dáhùn ìbéèrè kan táwọn èèyàn sábà máa ń béèrè tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù ní ìpínlẹ̀ yín.
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Jẹ́ káwọn ará mọ ohun tí wọ́n lè sọ tí onílé bá ní ọwọ́ òun dí.
Ìpadàbẹ̀wò Kejì—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv àfikún Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ìkọ̀sílẹ̀ àti Ìpínyà.
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 41 àti Àdúrà