ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 December ojú ìwé 6
  • December 24-30

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • December 24-30
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 December ojú ìwé 6

December 24-30

ÌṢE 17-18

  • Orin 78 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Fara Wé Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù Bó O Ṣe Ń Wàásù Tó O sì Ń Kọ́ni”: (10 min.)

    • Iṣe 17:2, 3​—Pọ́ọ̀lù máa ń báni fèrò wérò látinú Ìwé Mímọ́, ó sì máa ń tọ́ka nígbà tó bá ń kọ́ni (“fèrò-wérò” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 17:2; “fi ẹ̀rí ìdánilójú hàn nípasẹ̀ àwọn ìtọ́ka” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 17:3, nwtsty)

    • Iṣe 17:17​—Gbogbo ibi tí Pọ́ọ̀lù bá ti rí àwọn èèyàn ló ti máa ń wàásù (“ní ibi ọjà” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 17:17, nwtsty)

    • Iṣe 17:22, 23​—Pọ́ọ̀lù jẹ́ ẹni tó ní àkíyèsí, ibi tí ọ̀rọ̀ òun àtàwọn tó ń wàásù fún ti bara mu ló sì ti máa ń bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ̀ (“Sí Ọlọ́run Àìmọ̀” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 17:22, 23, nwtsty)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Iṣe 18:18​—Kí la lè sọ nípa ẹ̀jẹ́ tí Pọ́ọ̀lù jẹ́? (w08 5/15 32 ¶5)

    • Iṣe 18:21​—Báwo la ṣe lè fara wé Pọ́ọ̀lù bá a ṣe ń lé àwọn àfojúsùn nínú ìjọsìn Jèhófà? (“bí Jèhófà bá fẹ́” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 18:21, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣe 17:1-15

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Sọ̀rọ̀ nípa fídíò náà Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀ (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó).

  • Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwọ ni kó o yan ẹsẹ ìwé mímọ́ tó o máa lò, fi ọ̀kan nínú àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ lọ̀ ọ́.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jl ẹ̀kọ́ 7

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 70

  • Wàásù Ìhìn Rere Náà Kúnnákúnná, Kó O Sì Máa Kọ́ni: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ìjọsìn Ìdílé: Pọ́ọ̀lù​—Wàásù Ìhìn Rere Nípa Kristi Kúnnákúnná. Lẹ́yìn náà béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Báwo ni ìdílé tá a rí nínú fídíò yẹn ṣe rí i pé ó yẹ káwọn fi kún ìtara wọn lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù? Àwọn ọ̀nà wo ni wọ́n gbà tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ wọn? Àwọn ìbùkún wo ni wọ́n rí? Àwọn àbá wo lẹ rí tí ẹ̀yin náà lè tẹ̀ lé nígbà ìjọsìn ìdílé yín?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh Ṣé Ohun Tí Ọlọ́run Fẹ́ Kó Máa Ṣẹlẹ̀ Nìyí? àti orí 1 ¶1-5

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 151 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́