September 23-29
HÉBÉRÙ 12-13
Orin 88 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ìbáwí Máa Ń Fi Hàn Pé Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Wa”: (10 min.)
Heb 12:5—Má ṣe rẹ̀wẹ̀sì tí wọ́n bá bá ẹ wí (w12 3/15 29 ¶18)
Heb 12:6, 7—Ẹni tí Jèhófà nífẹ̀ẹ́ ló máa ń bá wí (w12 7/1 21 ¶3)
Heb 12:11—Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìbáwí máa ń dunni, síbẹ̀ ó máa jẹ́ ká sunwọ̀n sí i (w18.03 32 ¶18)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Heb 12:1—Báwo ni àpẹẹrẹ “àwọsánmà àwọn ẹlẹ́rìí tó pọ̀ gan-an” ṣe ń fún wa níṣìírí? (w11 9/15 17-18 ¶11)
Heb 13:9—Kí ni ẹsẹ yìí túmọ̀ sí? (w89 12/15 22 ¶10)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Heb 12:1-17 (th ẹ̀kọ́ 11)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Kejì—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 2)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 34-35 ¶19 (th ẹ̀kọ́ 6)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
À Ń Fara Dà Á Láìka . . . Àìpé Tiwa Fúnra Wa: (5 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò àwọn ìbéèrè yìí:
Ìwà wo ló ṣòro fún Arákùnrin Cázares láti kápá látìgbà tó ti ṣèrìbọmi?
Àwọn ọ̀nà wo ni Jèhófà gbà bá a wí?
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (10 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 10 ¶16-19
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 74 àti Àdúrà