October 21-27
1 PÉTÉRÙ 3-5
Orin 14 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Òpin Ohun Gbogbo Ti Sún Mọ́lé”: (10 min.)
1Pe 4:7—“Ẹ máa ronú jinlẹ̀, kí ẹ sì wà lójúfò, kí ẹ lè máa gbàdúrà” (w13 11/15 3 ¶1)
1Pe 4:8—“Ẹ ní ìfẹ́ tó jinlẹ̀ fún ara yín” (w99 4/15 22 ¶3)
1Pe 4:9—“Ẹ máa ṣe ara yín lálejò láìráhùn” (w18.03 14-15 ¶2-3)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
1Pe 3:19, 20—Ìgbà wo ni Jésù wàásù fún “àwọn ẹ̀mí tó wà lẹ́wọ̀n,” báwo ló sì ṣe ṣe é? (w13 6/15 23)
1Pe 4:6—Àwọn wo ni “òkú” tá a “kéde ìhìn rere” fún? (w08 11/15 21 ¶8)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Pe 3:8-22 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 6)
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? lẹ́yìn náà, kẹ́ ẹ jíròrò rẹ̀. (th ẹ̀kọ́ 8)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ìwà Mímọ́ àti Ọ̀wọ̀ Tó Jinlẹ̀ Máa Ń Yíni Lọ́kàn Pa Dà”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Jèhófà Ń Fún Wa Lókun Ká Lè Gbé Ẹrù Wa.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 11 ¶19-21
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 61 àti Àdúrà