ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 March ojú ìwé 2
  • March 1-7

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 1-7
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 March ojú ìwé 2

March 1-7

NỌ́ŃBÀ 7-8

  • Orin 4 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Bí Jèhófà Ṣe Ṣètò Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Nọ 8:17​—Ọwọ́ wo ni Jèhófà fi mú gbogbo àkọ́bí ọkùnrin àwọn ọmọ Ísírẹ́lì? (it-1 835)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Nọ 7:​1-17 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi: (2 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 11)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Ṣèbẹ̀wò sọ́dọ̀ ẹnì kan tó nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ rẹ, tó sì gba ìwé ìkésíni. (th ẹ̀kọ́ 6)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Ṣèbẹ̀wò sọ́dọ̀ ẹni tó ò ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tẹ́lẹ̀, kó o sì pè é wá sí Ìrántí Ikú Kristi. (th ẹ̀kọ́ 12)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Bá mọ̀lẹ́bí ẹ tó o ti wàásù fún nígbà kan rí sọ̀rọ̀, kó o sì pè é wá sí Ìrántí Ikú Kristi. (th ẹ̀kọ́ 17)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 54

  • Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (5 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù March.

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (10 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 5 ¶17-22 àti àpótí 5A

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 127 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́