ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 March ojú ìwé 4
  • March 15-21

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 15-21
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 March ojú ìwé 4

March 15-21

NỌ́ŃBÀ 11-12

  • Orin 46 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Ká Máa Ráhùn?”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Nọ 11:​7, 8​—Àwọn nǹkan wo la lè sọ nípa Jèhófà tá a bá ronú nípa bí mánà ṣe rí? (it-2 309)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Nọ 11:​1-15 (th ẹ̀kọ́ 2)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Tẹ́ni náà bá nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ rẹ, ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Ìrántí Ikú Jésù, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀ (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó). (th ẹ̀kọ́ 11)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Ṣèbẹ̀wò sọ́dọ̀ ẹnì kan tó nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ rẹ, tó sì gba ìwé ìkésíni. (th ẹ̀kọ́ 4)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Lẹ́yìn tí Ìrántí Ikú Kristi parí, fọgbọ́n bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ pẹ̀lú ẹnì kan tó wá síbẹ̀, kó o sì dáhùn ìbéèrè tó béèrè nípa bá a ṣe ṣèpàdé náà. (th ẹ̀kọ́ 2)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 19

  • “Ṣé Ò Ń Múra Sílẹ̀ fún Ìrántí Ikú Kristi?”: (15 min.) Ìjíròrò. Sọ àwọn ìfilọ̀ tẹ́ ẹ bá ní nípa bẹ́ ẹ ṣe máa ṣe Ìrántí Ikú Kristi. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Bó O Ṣe Lè Ṣe Búrẹ́dì Ìrántí Ikú Kristi.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 6 ¶7-13 àti àpótí 6A

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 70 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́