ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 March ojú ìwé 11
  • April 12-18

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • April 12-18
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 March ojú ìwé 11

April 12-18

NỌ́ŃBÀ 20-21

  • Orin 114 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jẹ́ Oníwà Pẹ̀lẹ́ Kódà Nígbà Tí Kò Bá Rọrùn”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Nọ 20:​23-27​—Kí la rí kọ́ látinú bí Áárónì ṣe hùwà pa dà nígbà tí Jèhófà bá a wí àti ojú tí Jèhófà fi wo Áárónì láìka àṣìṣe rẹ̀ sí? (w14 6/15 26 ¶12)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Nọ 20:​1-13 (th ẹ̀kọ́ 2)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 12)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún un ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 3)

  • Àsọyé: (5 min.) g 3/15 9​—Àkòrí: Bó O Ṣe Lè Kápá Ìbínú Rẹ? (th ẹ̀kọ́ 16)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 90

  • Máa Sọ “Ọ̀rọ̀ Tó Ń Gbéni Ró” Fáwọn Míì: (7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Tá a bá ń sọ̀rọ̀ ìbàjẹ́ tàbí tá à ń ráhùn, báwo nìyẹn ṣe lè ṣàkóbá fáwọn míì? Kí ló ran arákùnrin yẹn lọ́wọ́ láti ṣe àtúnṣe tó yẹ?

  • Má Ṣe Jẹ́ Kí Àwọn Ẹgbẹ́ Ẹ Ba Ìwà Ẹ Jẹ́!: (8 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò eré ojú pátákó náà. Lẹ́yìn náà, béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Àwọn nǹkan wo làwọn èèyàn lè fúngun mọ́ wa láti ṣe? Ìmọ̀ràn wo ló wà nínú Ẹ́kísódù 23:2? Àwọn nǹkan mẹ́rin wo la lè ṣe táwọn ojúgbà wa ò fi ní mú ká ṣe ohun tí kò dáa?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 7 ¶16-23

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 129 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́