July 18-24
2 SÁMÚẸ́LÌ 22
Orin 4 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Gbára Lé Jèhófà fún Ìrànlọ́wọ́”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
2Sa 22:36—Báwo ni ìrẹ̀lẹ̀ Jèhófà ṣe sọ Dáfídì di ẹni ńlá? (w12 11/15 17 ¶7)
Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Sa 22:33-51 (th ẹ̀kọ́ 10)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹni náà ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 1)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Lẹ́yìn náà, fún ẹni náà ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì, kó o sì ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 3)
Àsọyé: (5 min.) w06 8/15 21 ¶7-8—Àkòrí: Ṣé Sátánì Ló Ń Fa Gbogbo Ìṣòro Tó Bá Dé Bá Wa? (th ẹ̀kọ́ 13)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Máa Yọ̀ Nítorí Àwọn Iṣẹ́ Ìgbàlà Jèhófà: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, bi àwọn ará láwọn ìbéèrè yìí: Báwo ni Jèhófà ṣe ran ìdílé Arákùnrin Ganeshalingam lọ́wọ́ lásìkò tí wọ́n ń ja ogun abẹ́lé ní Siri Láńkà? Kí lo rí kọ́ nínú ìrírí yìí tó fún ìgbàgbọ́ ẹ lókun?
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (10 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ohun tó o kọ́ ní apá 1
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 60 àti Àdúrà