July 25-31
2 SÁMÚẸ́LÌ 23-24
Orin 76 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Kí Lo Máa Yááfì fún Jèhófà?”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
2Sa 23:15-17—Kí nìdí tí Dáfídì fi kọ̀ láti mu omi táwọn ọkùnrin ẹ̀ gbé wá? (w05 5/15 19 ¶6)
Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Sa 23:1-12 (th ẹ̀kọ́ 11)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Fi ẹ̀yìn ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò. Sọ fún ẹni náà pé wàá pa dà wá dáhùn ìbéèrè tó wà ní àkòrí ẹ̀kọ́ 01. (th ẹ̀kọ́ 9)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Pa dà lọ sọ́dọ̀ ẹnì kan tó gba ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì, kó o sì fi bá a ṣe ń ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì hàn án. (th ẹ̀kọ́ 3)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff kókó pàtàkì ní ẹ̀kọ́ 05, kí lo rí kọ́? àti ohun tó yẹ kó o ṣe (th ẹ̀kọ́ 19)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ẹ Jẹ́ Ká Máa Fi Tinútinú Ṣe Ìrúbọ (Sm 54:6): (9 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà.
Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Máa Lo Ara Ẹ Fáwọn Míì: (6 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, tó bá ṣeé ṣe, pe àwọn ọmọdé bíi mélòó kan, kó o sì bi wọ́n láwọn ìbéèrè yìí: Ibo ni Kọ́lá àti Tósìn fẹ́ lọ tẹ́lẹ̀ àmọ́ tí wọn ò lọ mọ́ torí bàbá àgbàlagbà yẹn? Báwo ni àpẹẹrẹ Jésù ṣe ran Kọ́lá lọ́wọ́? Àwọn nǹkan wo ni ìwọ náà ti ṣe fún Jèhófà àtàwọn míì?
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 13 àti àlàyé ìparí ìwé 1
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 32 àti Àdúrà