August 15-21
1 ÀWỌN ỌBA 5-6
Orin 122 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Wọ́n Fi Gbogbo Ọkàn sí Iṣẹ́ Ilé Náà”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
1Ọb 6:1—Kí ni ẹsẹ yìí jẹ́ ká mọ̀ nípa Bíbélì? (g 5/12 17, àpótí)
Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Ọb 5:1-12 (th ẹ̀kọ́ 12)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Fi ẹ̀yìn ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò. Sọ fún ẹni náà pé wàá pa dà wá dáhùn ìbéèrè tó wà ní àkòrí ẹ̀kọ́ 01. (th ẹ̀kọ́ 11)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Pa dà lọ sọ́dọ̀ ẹnì kan tó gba ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì, kó o sì fi bá a ṣe ń ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì hàn án. (th ẹ̀kọ́ 2)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 06 kókó 5 (th ẹ̀kọ́ 9)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
A Rọ́wọ́ Jèhófà Lára Wa Nígbà Tá À Ń Kọ́ Àwọn Gbọ̀ngàn Ìjọba: (15 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, bi àwọn ará pé: Àwọn nǹkan wo ló ṣẹlẹ̀ tó fi hàn pé Jèhófà bù kún iṣẹ́ kíkọ́ Gbọ̀ngàn Ìjọba ní Micronesia? Báwo ni ẹ̀mí mímọ́ ṣe ran àwọn ará tó ń kọ́ àwọn ilé ètò Ọlọ́run lọ́wọ́? Àwọn nǹkan wo ló mú kó o gbà pé Jèhófà bù kún iṣẹ́ ìkọ́lé ètò Ọlọ́run tó o ti lọ́wọ́ sí?
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 16
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 20 àti Àdúrà