September 12-18
1 ÀWỌN ỌBA 11-12
Orin 137 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Fi Ọgbọ́n Yan Ẹni Tó O Máa Fẹ́”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
1Ọb 12:21-24—Kí la rí kọ́ nínú bí Ọba Rèhóbóámù ṣe tẹ̀ lé àṣẹ Jèhófà? (w18.06 14 ¶1-4)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Ọb 12:21-33 (th ẹ̀kọ́ 10)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ fún àkànṣe ìwàásù láti bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ni kó o lò. (th ẹ̀kọ́ 3)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Máa bá ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kan tó o bẹ̀rẹ̀ nígbà àkọ́kọ́ nìṣó, kẹ́ ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 01 nínú ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 11)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 07 kókó 4 (th ẹ̀kọ́ 8)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Jèhófà Fẹ́ Kí Ìgbéyàwó Wà Pẹ́ Títí”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Bó O Ṣe Lè Múra Sílẹ̀ fún Ìgbéyàwó—Apá 3: Ṣírò Ohun Tó Máa Ná Ẹ.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 19 kókó 1-4
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 63 àti Àdúrà