September 19-25
1 ÀWỌN ỌBA 13-14
Orin 21 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Ní Ìtẹ́lọ́rùn, Ká sì Mọ̀wọ̀n Ara Wa?”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
1Ọb 14:13—Kí ni ẹsẹ Bíbélì yìí kọ́ wa nípa Jèhófà? (w10 7/1 29 ¶5)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Ọb 13:1-10 (th ẹ̀kọ́ 10)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ fún àkànṣe ìwàásù láti bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ẹni náà sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 7)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Máa bá ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kan tó o bẹ̀rẹ̀ nígbà àkọ́kọ́ nìṣó, kẹ́ ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 01 nínú ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 9)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 07 kókó 5 (th ẹ̀kọ́ 19)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Jẹ́ Kó Dá Ẹ Lójú Pé O Lè Fara Da Ìṣòro Àìlówó Lọ́wọ́”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Kọ́ Ilé Tó Máa Wà Pẹ́ Títí—“Ní Ìtẹ́lọ́rùn Pẹ̀lú Àwọn Nǹkan Ìsinsìnyí.”
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 19 kókó 5-6, kókó pàtàkì, kí lo rí kọ́? àti ohun tó yẹ kó o ṣe
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 56 àti Àdúrà