ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 September ojú ìwé 10
  • October 10-16

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • October 10-16
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 September ojú ìwé 10

October 10-16

1 ÀWỌN ỌBA 19-20

  • Orin 33 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jẹ́ Kí Jèhófà Tù Ẹ́ Nínú”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • 1Ọb 19:19-21—Kí la rí kọ́ nínú ìtàn yìí nípa ohun tó yẹ ká ṣe tí wọ́n bá fún wa láǹfààní iṣẹ́ ìsìn tuntun kan nínú ètò Ọlọ́run? (w97 11/1 31 ¶1)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Ọb 19:1-14 (th ẹ̀kọ́ 12)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Fídíò Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ìpadàbẹ̀wò: Bíbélì—Job 26:7. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì dáhùn ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o lò. (th ẹ̀kọ́ 18)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 07 kókó 7 àti Àwọn Kan Sọ Pé (th ẹ̀kọ́ 7)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 145

  • Máa Fi Ojú Tó Tọ́ Wo Nǹkan: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, bi àwọn ará pé: Àwọn ìlànà Bíbélì wo ló máa ràn wá lọ́wọ́ ká lè máa fojú tó tọ́ wo nǹkan? Báwo ni Jèhófà ṣe tu Èlíjà nínú? Báwo ni Jèhófà ṣe ń ràn wá lọ́wọ́ tó sì ń tù wá nínú?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 22

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 57 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́