October 17-23
1 ÀWỌN ỌBA 21-22
Orin 134 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Fara Wé Bí Jèhófà Ṣe Ń Lo Ọlá Àṣẹ Rẹ̀”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
1Ọb 21:27-29—Kí ló jẹ́ ká mọ̀ pé Áhábù ò ronú pìwà dà tọkàntọkàn? (w21.10 3 ¶4-6)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Ọb 22:24-38 (th ẹ̀kọ́ 2)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fi ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ ẹni náà, kó o sì lo ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 4)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹni náà ni ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì, kẹ́ ẹ sì bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní ẹ̀kọ́ 01. (th ẹ̀kọ́ 6)
Àsọyé: (5 min.) w15 3/15 9-11 ¶10-12—Àkòrí: Kí La Rí Kọ́ Nínú Bí Nábótì Ṣe Jẹ́ Olóòótọ́? (th ẹ̀kọ́ 14)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ìfẹ́ Máa Ń Ní Sùúrù àti Inú Rere”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Kí ni Alexandru ṣe tó fi hàn pé ó ní sùúrù àti inú rere bó tiẹ̀ jẹ́ pé òun ni olórí ìdílé? Kí ló mú kí Dorina yíwà pa dà nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín? Kí la rí kọ́ látinú ìrírí wọn?
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 23
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 50 àti Àdúrà