ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 March ojú ìwé 6
  • March 27–April 2

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 27–April 2
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 March ojú ìwé 6

March 27–April 2

2 KÍRÓNÍKÀ 5-7

  • Orin 129 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ọkàn Mi Á Máa Wà Níbẹ̀ Nígbà Gbogbo”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • 2Kr 6:29, 30​—Kí nìdí tí àwọn ọ̀rọ̀ tí Sólómọ́nì sọ nínú àdúrà ẹ̀ fi lè tù wá nínú? (w10 12/1 11 ¶7)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Kr 6:28-42 (th ẹ̀kọ́ 11)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Tẹ́ni náà bá nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ rẹ, ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Ìrántí Ikú Jésù, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀ (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó). (th ẹ̀kọ́ 3)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Lẹ́yìn tí Ìrántí Ikú Kristi parí, lọ sọ́dọ̀ ẹnì kan tó o pè, kó o wá dáhùn ìbéèrè tó béèrè nípa bẹ́ ẹ ṣe ṣèpàdé náà. (th ẹ̀kọ́ 17)

  • Àsọyé: (5 min.) w93 2/1 31​—Àkòrí: Tá Ò Bá Lè Lọ Síbi Ìrántí Ikú Kristi Fáwọn Ìdí Kan, Kí Ló Yẹ Ká Ṣe? (th ẹ̀kọ́ 18)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 36

  • “Dáàbò Bo Ọkàn Rẹ”: (10 min.) Ìjíròrò àti fídíò.

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 41 kókó 5 àti kókó pàtàkì, kí lo rí kọ́, àti ohun tó yẹ kó o ṣe

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 34 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́