ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 May ojú ìwé 10
  • June 5-11

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • June 5-11
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 May ojú ìwé 10

June 5-11

2 KÍRÓNÍKÀ 30-31

  • Orin 87 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ó Dáa Ká Máa Lọ Sípàdé”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • 2Kr 30:20​—Kí la rí kọ́ látinú bí Jèhófà ṣe tẹ́tí sí Hẹsikáyà? (w18.09 6 ¶14-15)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Kr 31:11-21 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. (th ẹ̀kọ́ 20)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹnì náà ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!​—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì, kó o sì bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ ní ẹ̀kọ́ 01. (th ẹ̀kọ́ 18)

  • Àsọyé: (5 min.) w19.01 11-12 ¶13-18​—Àkòrí: Bó O Ṣe Lè Fi Ìdáhùn Ẹ Yin Jèhófà Láwọn Ìpàdé. (th ẹ̀kọ́ 16)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 74

  • Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Múra Ohun Tó O Máa Sọ ní Ìpàdé Sílẹ̀: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà. Tó bá ṣeé ṣe bi àwọn ọmọdé pé: Báwo lo ṣe lè múra sílẹ̀ láti dáhùn nípàdé? Kí ló lè mú kí inú ẹ dùn tí wọn ò bá tiẹ̀ pè ẹ́ nípàdé?

  • Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù June.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ohun tó o kọ́ ní apá 3

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 115 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́