ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb24 September ojú ìwé 12
  • October 14-20

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • October 14-20
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2024
mwb24 September ojú ìwé 12

OCTOBER 14-20

SÁÀMÙ 96-99

Orin 66 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. “Ẹ Máa Kéde Ìhìn Rere”!

(10 min.)

Máa sọ ìhìn rere náà fáwọn èèyàn (Sm 96:2; w11 3/1 6 ¶1-2)

Sọ ìròyìn ayọ̀ nípa Ọjọ́ Ìdájọ́ fún wọn (Sm 96:12, 13; w12 9/1 16 ¶1)

Jẹ́ kí wọ́n mọ̀ pé ohun tó jẹ́ ìfẹ́ Ọlọ́run ni pé kí àwọn èèyàn táá máa yin orúkọ rẹ̀ kún ayé (Sm 99:1-3; w12 9/15 12 ¶18-19)

Arákùnrin àgbàlagbà kan ń bá ọkùnrin kan sọ̀rọ̀ níbi ìgbafẹ́.

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Sm 96:1—Láwọn ibi tí ọ̀rọ̀ náà “orin tuntun” ti fara hàn nínú Bíbélì, kí ló sábà máa ń túmọ̀ sí? (it-2 994)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

(4 min.) Sm 98:1–99:9 (th ẹ̀kọ́ 11)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Fọwọ́ Pàtàkì Mú Ìkẹ́kọ̀ọ́—Ohun Tí Jésù Ṣe

(7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò lmd ẹ̀kọ́ 10 kókó 1-2.

5. Fọwọ́ Pàtàkì Mú Ìkẹ́kọ̀ọ́—Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù

(8 min.) Ìjíròrò tó dá lórí lmd ẹ̀kọ́ 10 kókó 3-5 àti “Tún Wo.”

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 9

6. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

7. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

(30 min.) bt orí 16 ¶10-18

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 67 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́