Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì Jw.Org
ǸJẸ́ O MỌ̀?
Àwọn Òfin Ọlọ́run Lórí Ìmọ́tótó Là Wọ́n Lójú Gan-an
Orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì àtijọ́ jàǹfààní gan-an bí wọ́n ṣe ń pa àwọn òfin Ọlọ́run mọ́ lórí ọ̀rọ̀ ìmọ́tótó.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌMỌ̀ SÁYẸ́ǸSÌ ÀTI BÍBÉLÌ > BÍ BÍBÉLÌ ṢE BÁ ÌMỌ̀ SÁYẸ́ǸSÌ MU.
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Bá Àwọn Òbí Mi Sọ̀rọ̀ Nípa Àwọn Òfin Tí Wọ́n Ṣe?
Kọ́ bó o ṣe lè bá àwọn òbí ẹ sọ̀rọ̀ tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀, ohun rere tó máa tibẹ̀ yọ lè yà ẹ́ lẹ́nu.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > Ọ̀DỌ́ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ.