Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?
Kí ni àwọn onímọ̀ ẹ̀rọ rí lára labalábá cabbage white tó ràn wọ́n lọ́wọ́ láti ṣe àwọn páànù solar tó túbọ̀ gbéṣẹ́?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌMỌ̀ SÁYẸ́ǸSÌ ÀTI BÍBÉLÌ > TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Tí tọkọtaya ò bá gbọ́ra wọn yé, báwo ni wọ́n ṣe lè yanjú ẹ̀, kí wọ́n sì wà lálàáfíà pẹ̀lú ara wọn?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÌGBÉYÀWÓ ÀTI ÌDÍLÉ > ÌGBÉYÀWÓ.