Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì Jw.Org
ÌRÍRÍ
Bó tiẹ̀ jẹ́ pé Irma ti fẹ́rẹ̀ẹ́ pé ẹni àádọ́rùn-ún (90) ọdún, àwọn lẹ́tà rẹ̀ tó dá lórí Bíbélì wọ ọ̀pọ̀ àwọn tó ń kọ ọ́ sí lọ́kàn.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí NÍPA WA > ÌRÍRÍ > WỌ́N Ń KỌ́NI NÍ ÒTÍTỌ́ BÍBÉLÌ.
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Báwo Ni Eré Ìmárale Ṣe Lè Máa Wù Mí Ṣe?
Yàtọ̀ sí ìlera tó dá ṣáṣá, ǹjẹ́ àǹfààní míì wà nínú kéèyàn máa ṣeré ìmárale déédéé?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > Ọ̀DỌ́ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ.