Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
SEPTEMBER 2020
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: NOVEMBER 2–DECEMBER 6, 2020
© 2020 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Àwọn arábìnrin tó nítara máa ń kópa nínú ìpàdé, wọ́n máa ń lọ sóde ẹ̀rí, wọ́n máa ń tún Gbọ̀ngàn Ìjọba ṣe, wọ́n sì máa ń fìfẹ́ hàn sáwọn ará míì (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 39, ìpínrọ̀ 1)