Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
ÌRÍRÍ
Ìyá kan wá ọgbọ́n dá sí bó ṣe máa kọ́ àwọn ọmọ ẹ̀ ní ẹ̀kọ́ Bíbélì.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí NÍPA WA > ÌRÍRÍ > WỌ́N JẸ́ OLÓÒÓTỌ́ NÍGBÀ ÀDÁNWÒ.
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Dín Bí Mo Ṣe Sanra Kù?
Tó o bá fẹ́ dín bó o ṣe sanra kù, kọ́ bó o ṣe lè gbé ìgbé ayé tó yàtọ̀ kì í ṣe kó o ṣètò oúnjẹ àrà ọ̀tọ̀ kan.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > Ọ̀DỌ́ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ.