Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA
Ọkọ̀ Ojú Omi Lightbearer Tan Ìmọ́lẹ̀ Òtítọ́ Dé Ilẹ̀ Éṣíà
Láìka àtakò sí, àwọn kéréje tó wà nínú ọkọ̀ ojú omi Lightbearer fi ìgboyà fún irúgbìn Ìjọba Ọlọ́run ní ọ̀pọ̀ ilẹ̀ táwọn èèyàn tó pọ̀ ń gbé.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA.
TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?
Kí ló mú kí awọ ẹja inú òkun yìí máa yi kó sì máa rọ̀ nígbà míì?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?