Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JANUARY 2021
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: MARCH 1–APRIL 4, 2021
© 2020 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Ogunlọ́gọ̀ èèyàn tí wọ́n wọ aṣọ funfun tí wọ́n sì mú imọ̀ ọ̀pẹ dání dúró níwájú ìtẹ́ ògo Ọlọ́run àti níwájú Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 3, ìpínrọ̀ 7)