Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
ÌRÍRÍ
Àlùfáà Kan Rí Ìdáhùn sí Ìbéèrè Rẹ̀
Àlùfáà kan àti ìyàwó ẹ̀ sunkún gan-an lẹ́yìn tí ọmọkùnrin wọn kú. Àmọ́ kò pẹ́ tí wọ́n fi rí ìdáhùn tó tẹ́ wọn lọ́rùn sáwọn ìbéèrè tí wọ́n ní nípa ikú.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > ÌRÍRÍ ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ > WỌ́N Ń KỌ́NI NÍ ÒTÍTỌ́ BÍBÉLÌ.
OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ
Ṣé òfin “ojú fún ojú” fún àwọn èèyàn láṣẹ láti gbẹ̀san ara wọn?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ > BÍBÉLÌ.