Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
ÌRÍRÍ
Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà lórílẹ̀-èdè Guatemala mú òtítọ́ Bíbélì dé ọ̀dọ̀ àwọn tó ń sọ èdè Kekchi.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > ÌRÍRÍ ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ > WỌ́N Ń KỌ́NI NÍ ÒTÍTỌ́ BÍBÉLÌ.
BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ
Ẹ̀rọ Kékeré Tó Ń Mú Kí Ìgbàgbọ́ Àwọn Èèyàn Túbọ̀ Lágbára
Ọ̀pọ̀ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ti ń wa àwọn ìwé àtàwọn fídíò jáde lórí ìkànnì báyìí láìlo Íńtánẹ́ẹ̀tì.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ.