Àwọn Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì JW.ORG
BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ
Àwọn Èèyàn Ń Jàǹfààní Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì Kárí Ayé
A ní ilé ẹ̀kọ́ pàtàkì kan nílùú New York, àmọ́ kárí ayé làwọn akẹ́kọ̀ọ́ ti máa ń wá síbẹ̀. Báwo làwọn akẹ́kọ̀ọ́ ṣe máa ń débẹ̀?
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ.
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
Ìgbà kan wà tí Erwin Lamsfus bi ọ̀rẹ́ ẹ̀ kan pé, “Ǹjẹ́ o ti ronú nípa ìdí tá a fi wà láyé?” Ìdáhùn tó fún un yí ìgbésí ayé ẹ̀ pa dà.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ.