Ilé Ìṣọ́ Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JANUARY 2022
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: February 28–April 3, 2022
© 2021 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ẸSẸ ÌWÉ MÍMỌ́ TI ỌDÚN 2022:
‘Àwọn tó ń wá Jèhófà kò ní ṣaláìní ohun rere.’—SM. 34:10
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Nígbà ìpọ́njú ńlá, Gọ́ọ̀gù ti ilẹ̀ Mágọ́gù máa gbìyànjú láti ya wọlé wa, kí wọ́n lè rẹ́yìn wa. Àmọ́, ọkàn wa balẹ̀ pé Jésù àtàwọn áńgẹ́lì rẹ̀ ń rí ohun tó ń ṣẹlẹ̀, wọ́n sì máa gbèjà wa (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 1, ìpínrọ̀ 13)