Àwọn Ohun Tó Wà Lórí JW Library àti Ìkànnì JW.ORG
ÌRÍRÍ ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
Ọdún kẹtàlélógún (23) rèé tí àìsàn ti mú kí ara Virginia rọ jọwọrọ. Àmọ́ ìrétí ọjọ́ iwájú tó ní ń tù ú nínú, ó sì ń jẹ́ kí ọkàn ẹ̀ balẹ̀.
Lórí JW Library, lọ sí PUBLICATIONS > ARTICLE SERIES > ÌRÍRÍ ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > ÌRÍRÍ ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ > WỌ́N Ń FARA DA ÌṢÒRO.
TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN
Ọlọ́run mí sí wòlíì obìnrin kan tó ń jẹ́ Míríámù láti ṣáájú àwọn obìnrin Ísírẹlì nínú orin ìṣẹ́gun tí wọ́n kọ ní Òkun Pupa. Ohun tá a kọ́ lára Míríámù ni pé ká nígboyà, ká nígbàgbọ́, ká sì jẹ́ onírẹ̀lẹ̀.
Lórí JW Library, lọ sí PUBLICATIONS > ARTICLE SERIES > TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN.
Lórí ìkànnì jw.org, lọ sí OHUN TÁ A NÍ > OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ > TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN.