Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
APRIL 2022
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: JUNE 6–JULY 3, 2022
© 2022 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Inú Yùníìsì ìyá Tímótì àti Lọ́ìsì ìyá rẹ̀ àgbà dùn gan-an bí wọ́n ṣe ń wò ó lọ́jọ́ tó ṣèrìbọmi (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 17, ìpínrọ̀ 1)