ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w22 May ojú ìwé 1-32
  • Ilé Ìṣọ́ Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ilé Ìṣọ́ Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2022
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2022
w22 May ojú ìwé 1-32
Ilé Ìṣọ́​​​ Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́, May 2022.

Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́

MAY 2022

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: JULY 4–AUGUST 7, 2022

© 2022 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania

Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.

Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.

ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:

Ìfihàn orí 21 sọ pé ìlú Jerúsálẹ́mù Tuntun tá a fi wé ọ̀kẹ́ méje ó lé ẹgbàajì (144,000) “ń ti ọ̀run sọ̀ kalẹ̀ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run.” Nígbà Ẹgbẹ̀rún Ọdún Ìṣàkóso Kristi, ó máa mú ọ̀pọ̀ ìbùkún wá fún aráyé (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 21, ìpínrọ̀ 14-16)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́