Àwọn Ohun Tó Wà Lórí JW Library àti Ìkànnì JW.ORG
BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ
À Ń Ṣèpàdé Látorí Ẹ̀rọ Ayélujára
Báwo ni ètò Ọlọ́run ṣe ran àwọn ìjọ lọ́wọ́ láti gba ìwé àṣẹ lọ́wọ́ iléeṣẹ́ Zoom kí wọ́n lè máa fi ṣèpàdé láì náwó tó pọ̀ jù?
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
“Mi Ò Kì Í Ṣe Òǹrorò Èèyàn Mọ́”
Kí ló mú kí Sébastien Kayira fi ìwà ipá tó ń hù tẹ́lẹ̀ sílẹ̀, tí ò sì mutí para mọ́?
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Bó o ṣe lè mọ̀ bóyá ìwọ àti ọmọ ẹ ti ṣe tán láti bójú tó ojúṣe yìí.