Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 24: August 8-14, 2022
2 Kò Sẹ́ni Tó Lè Dárí Jini Bíi Ti Jèhófà
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 25: August 15-21, 2022
8 Jèhófà Máa Ń Bù Kún Àwọn Tó Bá Ń Dárí Jini
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 26: August 22-28, 2022
14 Bí Ìfẹ́ Ṣe Lè Jẹ́ Ká Borí Ìbẹ̀rù
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 27: August 29, 2022–September 4, 2022
26 Jẹ́ Kí “Òfin Inú Rere” Máa Darí Rẹ
30 Ǹjẹ́ O Mọ̀?—Nígbà ayé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, báwo ni wọ́n ṣe ń ka oṣù àti ọdún?