Àwọn Ohun Tó Wà Lórí JW Library àti Ìkànnì JW.ORG
BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ
Àwọn Míṣọ́nnárì Ń Wàásù ní “Ibi Tó Jìnnà Jù Lọ ní Ayé”
Àwọn míṣọ́nnárì tó ju ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) ló ń ṣiṣẹ́ ìsìn níbi ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ kárí ayé. Báwo ni ètò Ọlọ́run ṣe ń bójú tó wọn?
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Nǹkan márùn-ún tó o lè ṣe tí ò ní jẹ́ kí iṣẹ́ ẹ da àárín ìwọ àti ẹni tẹ́ ẹ jọ ṣègbéyàwó rú.
ÌRÍRÍ ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
Wọ́n Lẹ Àmì Onígun Mẹ́ta Aláwọ̀ Pọ́pù Mọ́ Aṣọ Wọn
Kí nìdí táwọn olùkọ́ ilé ìwé kan fi máa ń dárúkọ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà tí wọ́n bá ń kọ́ àwọn ọmọ ilé ìwé wọn nípa ìwà ìkà tí wọ́n hù sáwọn èèyàn ní àgọ́ ìfìyàjẹni Násì?