Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
SEPTEMBER 2022
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: NOVEMBER 7–DECEMBER 4, 2022
© 2022 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Tá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Arákùnrin kan ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ nígbà Ẹgbẹ̀rún Ọdún Ìṣàkóso Kristi (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 39, ìpínrọ̀ 20)