Àwọn Ohun Tó Wà Lórí JW Library Àti Ìkànnì JW.ORG
BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ
Ètò Ìṣiṣẹ́ Tó Ní Gbogbo Ohun Tá A Nílò
Ṣé o fẹ́ mọ ohun tá a máa ń ṣe kí JW Library® lè máa ṣiṣẹ́ dáadáa, kó sì sunwọ̀n sí i?
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Ohun Tó O Lè Ṣe Tí Ẹnì Kejì Ẹ Bá Hùwà Tó Ń Múnú Bí Ẹ
Dípò tí wàá fi jẹ́ kí ìwà ọkọ tàbí ìyàwó ẹ dá ìjà sílẹ̀ láàárín yín, ṣe ni kó o gbìyànjú láti mọ ìdí tó fi ń hùwà yẹn, kó o sì ràn án lọ́wọ́.
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
Ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Antonio nígbà tó ń hùwà ipá, tó ń lo oògùn olóró, tó sì ń mu ọtí àmujù jẹ́ kó gbà pé asán layé yìí. Kí ló jẹ́ kó yí ìgbésí ayé ẹ̀ pa dà?