Ilé Ìṣọ́ Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JANUARY 2023
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: FEBRUARY 27–APRIL 2, 2023
© 2022 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ẸSẸ ÌWÉ MÍMỌ́ TI ỌDÚN 2023:
“Òtítọ́ ni kókó inú ọ̀rọ̀ rẹ.”—SM. 119:160
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò, àfi tá a bá sọ pé Bíbélì míì la lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Àwọn adàwékọ tó kọ Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù rí i dájú pé àwọn kọ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run lọ́nà tó péye (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 1, ìpínrọ̀ 5)