Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JULY 2023
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: SEPTEMBER 11–OCTOBER 8, 2023
© 2023 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò, àfi tá a bá sọ pé Bíbélì míì la lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Torí pé Bárákì àtàwọn ọmọ ogun ẹ̀ nígboyà, wọ́n lé àwọn ọmọ ogun Sísérà bá (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 31, ìpínrọ̀ 18)