Ilé Ìṣọ́ Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
SEPTEMBER 2023
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: NOVEMBER 6–DECEMBER 10, 2023
© 2023 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò, àfi tá a bá sọ pé Bíbélì míì la lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Jèhófà fún Sámúsìn lágbára láti gbéjà ko àwọn Filísínì (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 37, ìpínrọ̀ 15)