Ilé Ìṣọ́ Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
NOVEMBER 2023
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: JANUARY 8–FEBRUARY 4, 2024
© 2023 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò, àfi tá a bá sọ pé Bíbélì míì la lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Ẹ́sírà ń sunkún, inú ẹ̀ sì bà jẹ́ bó ṣe ń gbàdúrà nínú tẹ́ńpìlì nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn èèyàn Ọlọ́run. Àwọn èèyàn náà sì ń sunkún. Ṣẹkanáyà tu Ẹ́sírà nínú, ó sì fi dá a lójú pé: “Ìrètí ṣì wà fún Ísírẹ́lì. . . . A sì wà pẹ̀lú rẹ.”—Ẹ́sírà 10:2, 4 (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 48, ìpínrọ̀ 17)