Ilé Ìṣọ́ Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
DECEMBER 2023
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: FEBRUARY 5–MARCH 3, 2024
© 2023 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò, àfi tá a bá sọ pé Bíbélì míì la lò.
ÀWÒRÁN IWÁJÚ ÌWÉ:
Ọ̀pọ̀ àwọn ọ̀dọ́kùnrin àtàwọn ọ̀dọ́bìnrin tí wọ́n kẹ́kọ̀ọ́ látinú Ìwé Mímọ́ ń fi ohun tí wọ́n kọ́ sílò, wọ́n sì ti di Kristẹni tí òtítọ́ jinlẹ̀ nínú wọn (Wo àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 52, ìpínrọ̀ 21 àti àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ 53, ìpínrọ̀ 19-20)