Ilé Ìṣọ́ Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JANUARY 2024
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: MARCH 4–APRIL 7, 2024
© 2023 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ẸSẸ ÌWÉ MÍMỌ́ TI ỌDÚN 2024:
“Nígbà tí ẹ̀rù ń bà mí, mo gbẹ́kẹ̀ lé ọ.”—SM. 56:3.
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò, àfi tá a bá sọ pé Bíbélì míì la lò.