Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 18: July 8-14, 2024
2 Fọkàn Tán Ọlọ́run Aláàánú Tó Jẹ́ “Onídàájọ́ Gbogbo Ayé”!
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 19: July 15-21, 2024
8 Kí La Mọ̀ Nípa Bí Jèhófà Ṣe Máa Ṣèdájọ́ Lọ́jọ́ Iwájú?
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 20: July 22-28, 2024
14 Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Mú Kó O Máa Wàásù Nìṣó
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 21: July 29, 2024–August 4, 2024
20 Báwo Lo Ṣe Lè Rí Ẹni Tó O Máa Fẹ́?
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 22: August 5-11, 2024
26 Bó O Ṣe Lè Mọ̀ Bóyá Kó O Fẹ́ Ẹnì Kan Tàbí Kó O Má Fẹ́ Ẹ
32 Ohun Tó O Lè Kẹ́kọ̀ọ́ Nípa Ẹ̀—Bó O Ṣe Lè Fara Dà Á Tí Wọ́n Bá Rẹ́ Ẹ Jẹ