Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 48: February 3-9, 2025
2 Ohun Tá A Kọ́ Nígbà Tí Jésù Pèsè Búrẹ́dì Lọ́nà Ìyanu
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 49: February 10-16, 2025
8 Kí Ló Yẹ Kó O Ṣe Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé?
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 50: February 17-23, 2025
14 Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Ran Àwọn Ọmọ Yín Lọ́wọ́ Kí Ìgbàgbọ́ Wọn Lè Túbọ̀ Lágbára
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 51: February 24, 2025–March 2, 2025
20 Jèhófà Mọ Ohun Tó Ń Pa Ẹ́ Lẹ́kún
26 Ìtàn Ìgbésí Ayé—Gbogbo Ìgbà Ni Mò Ń Kẹ́kọ̀ọ́
30 Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
32 Ohun Tó O Lè Kẹ́kọ̀ọ́ Nípa Ẹ̀—Àwọn Olóòótọ́ Ìránṣẹ́ Jèhófà Máa Ń San Ẹ̀jẹ́ Wọn