Ilé Ìṣọ́ Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́
JANUARY 2025
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÁ A MÁA KẸ́KỌ̀Ọ́ NÍ: MARCH 3–APRIL 6, 2025
© 2024 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
ẸSẸ ÌWÉ MÍMỌ́ TI ỌDÚN 2025:
“Ẹ fún Jèhófà ní ògo tí ó yẹ orúkọ rẹ̀.”—SM. 96:8.
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì donate.jw.org.
Inú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Bíbélì tá a lò, àfi tá a bá sọ pé Bíbélì míì la lò.