Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí
Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2013
Tí Ó Sọ Ìròyìn Ọdún Iṣẹ́ Ìsìn 2012
Ìwé yìí jẹ́ ti ․․․․․
© 2013
WATCH TOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF PENNSYLVANIA.
Publishers
WATCHTOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF NEW YORK, INC. 25 Columbia Heights, Brooklyn, NY 11201-2483, U.S.A.
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn.
Ẹnì kan lára Ìgbìmọ̀ Tó Ń Ṣètò Ìrànwọ́ Nígbà Àjálù ní ìlú Yangon. Ó ń ṣàtúnṣe ilé tí Ìjì Ńlá Nargis bà jẹ́ (ojú ìwé 163)