Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Lẹ́tà Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí 4
Àwọn Ohun Pàtàkì Tó Ṣẹlẹ̀ Lọ́dún Tó Kọjá 9
Iṣẹ́ Ń Yára Tẹ̀ Síwájú Nílùú Warwick 11
Ẹ̀ka Tó Ń Yàwòrán Ilé Tó sì Ń Kọ́ Ọ Kárí Ayé 16
Ìkórajọ Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Tí Èrò Pọ̀ sí Jù Lọ 24
Ìyàsímímọ́ Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Orílẹ̀-Èdè Siri Láńkà 28
‘A Ti Rí Àwọn Ohun Àgbàyanu’ 42
À Ń Wàásù A Sì Ń Kọ́ni Kárí Ayé 45
Éṣíà àti Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn Ayé ILẸ̀ 58
Àlàyé Ṣókí Nípa Orílẹ̀-Èdè Dominican 82
Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Fìdí Múlẹ̀ 86
Ìjọba Fi Wọ́n Sẹ́wọ̀n Torí Wọ́n Kọ̀ Láti Wọṣẹ́ Ológun 94
Àwọn Míṣọ́nnárì Ń Báṣẹ́ Lọ Lábẹ́lẹ̀ 98
Àjọṣe Trujillo àti Ṣọ́ọ̀ṣì Kátólíìkì 104
‘Ẹ Lé Àwọn Olórí Wọn Kúrò Nílùú’ 109
Wọ́n ‘Jẹ́ Oníṣọ̀ọ́ra bí Ejò àti Ọlọ́rùn-Mímọ́ bí Àdàbà’ 114
“Mo Fìgboyà Jà Bíi Kìnnìún” 118
Ó Dá Mi Lójú Pé Ìjọba Ọlọ́run Máa Dé 120
Mi Ò Ní Yéé Jẹ́ Ẹlẹ́rìí Jèhófà 122
Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ti Múra Tán Láti Dúró sí Orílẹ̀-Èdè Dominican 128
A Mú Ìhìn Rere Dé Àwọn Ibi Jíjìnnà Réré 130
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Tọ́jú Àwọn Ará Wọn 138
Kí A Gba Gbogbo Onírúurú Ènìyàn Là 142
A Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Fi Èdè Creole ti Ilẹ̀ Haiti Wàásù 145
Ìmìtìtì Ilẹ̀ Tó Runlérùnnà Wáyé Lórílẹ̀-Èdè Haiti 149
À Ń Retí Bí Ọjọ́ Ọ̀la Ṣe Máa Rí 156
Jèhófà Mú Kí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Wá Kẹ́kọ̀ọ́ 160
Àwọn Méjìlélógún Fi Ṣọ́ọ̀ṣì Sílẹ̀ 162
Jagunjagun Tí Kò Gbà Pé Ọlọ́run Wà Di Ìránṣẹ́ Ọlọ́run 164
Adití Tó Kọ́kọ́ Kẹ́kọ̀ọ́ Òtítọ́ 166
Bí Mo Ṣe Mọ Ohun Tí Màá Fi Ayé Mi Ṣe 168