Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Lẹ́tà Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí 4
Àwọn Ohun Pàtàkì Tó Ṣẹlẹ̀ Lọ́dún Tó Kọjá 8
“Àwọn Ètò Orí Tẹlifíṣọ̀n JW Ti Lọ Wà Jù!” 10
Kíkọ́ Gbọ̀ngàn Ìjọba Lọ́nà Tó Túbọ̀ Yára 16
Báwo Ni Iṣẹ́ Ṣe Ń Lọ Sí Ní Warwick? 18
Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Dé Ọ̀dọ̀ Àwọn Tí A Kì Í Bá Nílé 20
A Ya Àwọn Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Wa Sí Mímọ́ 28
A Mú Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Jáde Láwọn Èdè Míì 30
À Ń Wàásù A Sì Ń Kọ́ni Kárí Ayé 44
Éṣíà àti Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn Ayé 58
Òwò Èròjà Amóúnjẹ-ta-sánsán 86
“Ibí Yìí Gan-an ni Màá ti Bẹ̀rẹ̀” 88
Bá A Ṣe Ń Wàásù Láyé Ọjọ́un 97
Ìwàásù Méso Jáde ní West Java 102
Lábẹ́ Àjàgà Ìjọba Ilẹ̀ Japan 108
Àwọn Míṣọ́nnárì Láti Gílíádì Dé 114
Iṣẹ́ Náà Gbòòrò dé Ìlà Oòrùn 119
Àwọn Míṣọ́nnárì Míì Tún Dé 123
Mo La Rògbòdìyàn Àwọn Kọ́múníìsì Já 129
Àádọ́ta Ọdún Lẹ́nu Iṣẹ́ Aṣáájú-Ọ̀nà Àkànṣe 130
Ọ̀gá Àwọn Jàǹdùkú Di Ọmọlúwàbí 131
Wọ́n Pinnu Láti Tẹ̀ Síwájú 132
Wọ́n Ò fi Ọ̀rọ̀ Ìpàdé Ṣeré 138
Wọ́n Ń Fayọ̀ Polongo Orúkọ Jèhófà 151
Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Wa Bọ́ sí Ojútáyé 158
Jèhófà Bù Kún Wa Ju Bá A Ṣe Rò Lọ! 168