RÚÙTÙ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Élímélékì àti ìdílé rẹ̀ kó lọ sí Móábù (1, 2)
Náómì, Ọ́pà àti Rúùtù di opó (3-6)
Rúùtù kò fi Náómì àti Jèhófà sílẹ̀ (7-17)
Náómì pa dà sí Bẹ́tílẹ́hẹ́mù, Rúùtù tẹ̀ lé e (18-22)
2
Rúùtù pèéṣẹ́ ní oko Bóásì (1-3)
Rúùtù àti Bóásì pàdé (4-16)
Rúùtù sọ fún Náómì bí Bóásì ṣe ṣojúure sí òun (17-23)
3
Náómì sọ ohun tí Rúùtù máa ṣe (1-4)
Rúùtù àti Bóásì ní ibi ìpakà (5-15)
Rúùtù pa dà sọ́dọ̀ Náómì (16-18)
4